Thursday, June 8, 2023

Hymn 12


  • 1. Iwo imole okan mi,
  • Ni odo Re, oru ko si,
  • Ki kuku aye ma bo O,
  • Kuro l'oju iranse Re.
  • .
  • 2. Ni gba t'orun ale didun
  • Ba npa ipenpe 'ju mi de,
  • K'ero mi je lati simi,
  • Lae l'aya Olugbala mi.
  • 3. Ba mi gbe l'oro tit'ale
  • Laisi Re, emi ko le wa,
  • Ba mi gbe 'gbat'ile ba nsu,
  • Laisi Re, emi ko ke ku.
  • .
  • 4. Bi otosi omo Re kan
  • Ba tapa s'oro Re loni,
  • Oluwa, sise ore Re,
  • Ma je k'o sun ninu ese
  • 5. Bukun fun awon alaisan,
  • Pese fun awon talaka,
  • K'orun onirobinuje
  • Dabi orun omo titun
  • .
  • 6. Sure fun wa ni gbat'a ji
  • Ka to m'ohun aye yi se
  • Titi awa o de 'b'ife
  • T'a o si de Ijoba Re.
  • .
  • AMIN

Hymn 12

1. Iwo imole okan mi, Ni odo Re, oru ko si, Ki kuku aye ma bo O, Kuro l'oju iranse Re. . 2. Ni gba t'orun ale didun Ba npa ipenpe ...